1 Pétérù 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Kódà, ọ̀nà yìí la pè yín sí, torí Kristi pàápàá jìyà torí yín,+ ó fi àpẹẹrẹ lélẹ̀ fún yín kí ẹ lè máa tọ ipasẹ̀ rẹ̀ pẹ́kípẹ́kí.+
21 Kódà, ọ̀nà yìí la pè yín sí, torí Kristi pàápàá jìyà torí yín,+ ó fi àpẹẹrẹ lélẹ̀ fún yín kí ẹ lè máa tọ ipasẹ̀ rẹ̀ pẹ́kípẹ́kí.+