1 Jòhánù 3:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Bákan náà, ẹni tó bá ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀, ó sì máa wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú ẹni náà.+ Ẹ̀mí tó fún wa sì jẹ́ ká mọ̀ pé ó wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú wa.+
24 Bákan náà, ẹni tó bá ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀, ó sì máa wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú ẹni náà.+ Ẹ̀mí tó fún wa sì jẹ́ ká mọ̀ pé ó wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú wa.+