Róòmù 14:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí èyí ni Kristi fi kú, tí ó sì pa dà wà láàyè, kí ó lè jẹ́ Olúwa lórí àwọn òkú àti àwọn alààyè.+ 1 Kọ́ríńtì 15:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí lára àwọn ohun tí mo kọ́kọ́ fi lé yín lọ́wọ́ ni ohun tí èmi náà gbà, pé Kristi kú nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa bí Ìwé Mímọ́ ṣe sọ;+ 4 àti pé a sin ín,+ bẹ́ẹ̀ ni, pé a jí i dìde+ ní ọjọ́ kẹta+ bí Ìwé Mímọ́ ṣe sọ;+
9 Torí èyí ni Kristi fi kú, tí ó sì pa dà wà láàyè, kí ó lè jẹ́ Olúwa lórí àwọn òkú àti àwọn alààyè.+
3 Nítorí lára àwọn ohun tí mo kọ́kọ́ fi lé yín lọ́wọ́ ni ohun tí èmi náà gbà, pé Kristi kú nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa bí Ìwé Mímọ́ ṣe sọ;+ 4 àti pé a sin ín,+ bẹ́ẹ̀ ni, pé a jí i dìde+ ní ọjọ́ kẹta+ bí Ìwé Mímọ́ ṣe sọ;+