Róòmù 1:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nítorí àárò yín ń sọ mí, kí n lè fún yín ní ẹ̀bùn ẹ̀mí, kí ẹ lè fìdí múlẹ̀; 12 àbí, ká kúkú sọ pé, ká jọ fún ara wa ní ìṣírí+ nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan wa, tiyín àti tèmi. Róòmù 15:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí kálukú wa máa ṣe ohun tó wu ọmọnìkejì rẹ̀ fún ire rẹ̀, láti gbé e ró.+
11 Nítorí àárò yín ń sọ mí, kí n lè fún yín ní ẹ̀bùn ẹ̀mí, kí ẹ lè fìdí múlẹ̀; 12 àbí, ká kúkú sọ pé, ká jọ fún ara wa ní ìṣírí+ nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan wa, tiyín àti tèmi.