Kólósè 4:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Tí ẹ bá ti ka lẹ́tà yìí láàárín yín, ẹ ṣètò pé kí wọ́n kà á+ nínú ìjọ àwọn ará Laodíkíà, kí ẹ̀yin náà sì ka èyí tó wá láti Laodíkíà.
16 Tí ẹ bá ti ka lẹ́tà yìí láàárín yín, ẹ ṣètò pé kí wọ́n kà á+ nínú ìjọ àwọn ará Laodíkíà, kí ẹ̀yin náà sì ka èyí tó wá láti Laodíkíà.