Mátíù 24:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà tó jókòó sórí Òkè Ólífì, àwọn ọmọ ẹ̀yìn wá bá a ní òun nìkan, wọ́n sọ pé: “Sọ fún wa, ìgbà wo ni àwọn nǹkan yìí máa ṣẹlẹ̀, kí ló sì máa jẹ́ àmì pé o ti wà níhìn-ín*+ àti ti ìparí ètò àwọn nǹkan?”*+
3 Nígbà tó jókòó sórí Òkè Ólífì, àwọn ọmọ ẹ̀yìn wá bá a ní òun nìkan, wọ́n sọ pé: “Sọ fún wa, ìgbà wo ni àwọn nǹkan yìí máa ṣẹlẹ̀, kí ló sì máa jẹ́ àmì pé o ti wà níhìn-ín*+ àti ti ìparí ètò àwọn nǹkan?”*+