1 Tẹsalóníkà 4:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ fi ṣe àfojúsùn yín láti máa ṣe jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́,+ ẹ má yọjú sí ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀,+ kí ẹ máa fi ọwọ́ yín ṣiṣẹ́,+ bí a ṣe sọ fún yín, 12 kí ẹ lè máa rìn lọ́nà tó bójú mu lójú àwọn tó wà níta,+ kí ẹ má sì ṣe aláìní ohunkóhun. 1 Tímótì 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ó dájú pé tí ẹnikẹ́ni kò bá pèsè fún àwọn tirẹ̀, pàápàá fún ìdílé rẹ̀, ó ti sẹ́ ìgbàgbọ́, ó sì burú ju ẹni tí kò ní ìgbàgbọ́.+
11 Ẹ fi ṣe àfojúsùn yín láti máa ṣe jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́,+ ẹ má yọjú sí ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀,+ kí ẹ máa fi ọwọ́ yín ṣiṣẹ́,+ bí a ṣe sọ fún yín, 12 kí ẹ lè máa rìn lọ́nà tó bójú mu lójú àwọn tó wà níta,+ kí ẹ má sì ṣe aláìní ohunkóhun.
8 Ó dájú pé tí ẹnikẹ́ni kò bá pèsè fún àwọn tirẹ̀, pàápàá fún ìdílé rẹ̀, ó ti sẹ́ ìgbàgbọ́, ó sì burú ju ẹni tí kò ní ìgbàgbọ́.+