1 Kọ́ríńtì 7:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Tóò, mo sọ fún àwọn tí kò gbéyàwó àti àwọn opó pé ó sàn kí wọ́n wà bí mo ṣe wà.+ 9 Àmọ́ tí wọn ò bá lè mára dúró, kí wọ́n gbéyàwó, torí ó sàn láti gbéyàwó ju kí ara ẹni máa gbóná nítorí ìfẹ́ ìbálòpọ̀.+
8 Tóò, mo sọ fún àwọn tí kò gbéyàwó àti àwọn opó pé ó sàn kí wọ́n wà bí mo ṣe wà.+ 9 Àmọ́ tí wọn ò bá lè mára dúró, kí wọ́n gbéyàwó, torí ó sàn láti gbéyàwó ju kí ara ẹni máa gbóná nítorí ìfẹ́ ìbálòpọ̀.+