Mátíù 13:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ní ti èyí tó bọ́ sáàárín àwọn ẹ̀gún, òun ló ń gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, àmọ́ tí àníyàn ètò àwọn nǹkan yìí*+ àti agbára ìtannijẹ ọrọ̀ fún ọ̀rọ̀ náà pa, kò sì so èso.+
22 Ní ti èyí tó bọ́ sáàárín àwọn ẹ̀gún, òun ló ń gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, àmọ́ tí àníyàn ètò àwọn nǹkan yìí*+ àti agbára ìtannijẹ ọrọ̀ fún ọ̀rọ̀ náà pa, kò sì so èso.+