2 Tẹsalóníkà 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn náà, a ó fi arúfin náà hàn, ẹni tí Jésù Olúwa máa fi ẹ̀mí ẹnu rẹ̀ pa,+ tí á sì sọ di asán nígbà tó bá ṣe kedere+ pé ó ti wà níhìn-ín. 2 Tímótì 4:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mo pàṣẹ tó rinlẹ̀ yìí fún ọ níwájú Ọlọ́run àti Kristi Jésù, ẹni tó máa ṣèdájọ́+ àwọn alààyè àti òkú,+ nípasẹ̀ ìfarahàn rẹ̀+ àti Ìjọba rẹ̀:+ 2 Tímótì 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Láti ìsinsìnyí lọ, a ti fi adé òdodo + pa mọ́ dè mí, èyí tí Olúwa, onídàájọ́ òdodo,+ máa fi san mí lẹ́san ní ọjọ́ yẹn,+ síbẹ̀ kì í ṣe fún èmi nìkan, àmọ́ fún gbogbo àwọn tó nífẹ̀ẹ́ ìfarahàn rẹ̀.
8 Lẹ́yìn náà, a ó fi arúfin náà hàn, ẹni tí Jésù Olúwa máa fi ẹ̀mí ẹnu rẹ̀ pa,+ tí á sì sọ di asán nígbà tó bá ṣe kedere+ pé ó ti wà níhìn-ín.
4 Mo pàṣẹ tó rinlẹ̀ yìí fún ọ níwájú Ọlọ́run àti Kristi Jésù, ẹni tó máa ṣèdájọ́+ àwọn alààyè àti òkú,+ nípasẹ̀ ìfarahàn rẹ̀+ àti Ìjọba rẹ̀:+
8 Láti ìsinsìnyí lọ, a ti fi adé òdodo + pa mọ́ dè mí, èyí tí Olúwa, onídàájọ́ òdodo,+ máa fi san mí lẹ́san ní ọjọ́ yẹn,+ síbẹ̀ kì í ṣe fún èmi nìkan, àmọ́ fún gbogbo àwọn tó nífẹ̀ẹ́ ìfarahàn rẹ̀.