Òwe 31:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Òòfà ẹwà lè jẹ́ èké, ẹwà ojú sì lè má tọ́jọ́,*+Àmọ́ obìnrin tó bẹ̀rù Jèhófà ló máa gba ìyìn.+