1 Tímótì 5:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Má fi ìkánjú gbé ọwọ́ lé ọkùnrin èyíkéyìí láé;*+ má sì pín nínú ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ẹlòmíì; jẹ́ oníwà mímọ́.
22 Má fi ìkánjú gbé ọwọ́ lé ọkùnrin èyíkéyìí láé;*+ má sì pín nínú ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ẹlòmíì; jẹ́ oníwà mímọ́.