1 Kọ́ríńtì 7:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Àmọ́ tí ẹnì kan bá rí i pé òun ti ń hùwà tí kò yẹ torí pé òun kò gbéyàwó,* tí onítọ̀hún sì ti kọjá ìgbà ìtànná èwe,* ohun tó yẹ kó ṣe nìyí: Kí ó ṣe ohun tí ó fẹ́; kò dẹ́ṣẹ̀. Kí wọ́n gbéyàwó.+ 1 Kọ́ríńtì 9:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 A ní ẹ̀tọ́ láti máa mú ìyàwó tó jẹ́ onígbàgbọ́*+ lẹ́yìn bíi ti àwọn àpọ́sítélì yòókù àti àwọn arákùnrin Olúwa + àti Kéfà,*+ àbí a kò ní?
36 Àmọ́ tí ẹnì kan bá rí i pé òun ti ń hùwà tí kò yẹ torí pé òun kò gbéyàwó,* tí onítọ̀hún sì ti kọjá ìgbà ìtànná èwe,* ohun tó yẹ kó ṣe nìyí: Kí ó ṣe ohun tí ó fẹ́; kò dẹ́ṣẹ̀. Kí wọ́n gbéyàwó.+
5 A ní ẹ̀tọ́ láti máa mú ìyàwó tó jẹ́ onígbàgbọ́*+ lẹ́yìn bíi ti àwọn àpọ́sítélì yòókù àti àwọn arákùnrin Olúwa + àti Kéfà,*+ àbí a kò ní?