ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìṣe 6:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ohun tí wọ́n sọ dùn mọ́ gbogbo àwọn èèyàn náà nínú, wọ́n sì yan Sítéfánù, ọkùnrin tó kún fún ìgbàgbọ́ àti ẹ̀mí mímọ́ pẹ̀lú Fílípì,+ Pírókórọ́sì, Níkánọ̀, Tímónì, Páménásì àti Níkóláósì tó jẹ́ aláwọ̀ṣe* ará Áńtíókù. 6 Wọ́n mú wọn wá sọ́dọ̀ àwọn àpọ́sítélì, lẹ́yìn tí àwọn àpọ́sítélì gbàdúrà, wọ́n gbé ọwọ́ lé wọn.+

  • Ìṣe 13:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Bí wọ́n ṣe ń ṣiṣẹ́ Jèhófà,* tí wọ́n sì ń gbààwẹ̀, ẹ̀mí mímọ́ sọ pé: “Ẹ ya Bánábà àti Sọ́ọ̀lù+ sọ́tọ̀ fún mi kí wọ́n lè ṣe iṣẹ́ tí mo pè wọ́n sí.”+ 3 Lẹ́yìn tí wọ́n gbààwẹ̀, tí wọ́n sì gbàdúrà, wọ́n gbé ọwọ́ lé wọn, wọ́n sì rán wọn lọ.

  • Ìṣe 19:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Nígbà tí Pọ́ọ̀lù gbé ọwọ́ lé wọn, ẹ̀mí mímọ́ bà lé wọn,+ wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í sọ èdè àjèjì, wọ́n sì ń sọ tẹ́lẹ̀.+

  • 2 Tímótì 1:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Torí èyí ni mo ṣe rán ọ létí pé kí o jẹ́ kí ẹ̀bùn Ọlọ́run tó wà nínú rẹ nígbà tí mo gbé ọwọ́ lé+ ọ máa jó bí iná.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́