1 Tímótì 5:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Tí obìnrin èyíkéyìí tó jẹ́ onígbàgbọ́ bá ní àwọn mọ̀lẹ́bí tó jẹ́ opó, kó ràn wọ́n lọ́wọ́, kí wọ́n má bàa di ẹrù ìjọ. Ìjọ á sì lè ṣèrànwọ́ fún àwọn tó jẹ́ opó ní tòótọ́.*+
16 Tí obìnrin èyíkéyìí tó jẹ́ onígbàgbọ́ bá ní àwọn mọ̀lẹ́bí tó jẹ́ opó, kó ràn wọ́n lọ́wọ́, kí wọ́n má bàa di ẹrù ìjọ. Ìjọ á sì lè ṣèrànwọ́ fún àwọn tó jẹ́ opó ní tòótọ́.*+