1 Kọ́ríńtì 4:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ìdí nìyẹn tí mo fi rán Tímótì sí yín, torí ó jẹ́ ọmọ mi ọ̀wọ́n àti olóòótọ́ nínú Olúwa. Á rán yín létí àwọn ọ̀nà tí mò ń gbà ṣe nǹkan* ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù,+ bí mo ṣe ń kọ́ni níbi gbogbo nínú gbogbo ìjọ.
17 Ìdí nìyẹn tí mo fi rán Tímótì sí yín, torí ó jẹ́ ọmọ mi ọ̀wọ́n àti olóòótọ́ nínú Olúwa. Á rán yín létí àwọn ọ̀nà tí mò ń gbà ṣe nǹkan* ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù,+ bí mo ṣe ń kọ́ni níbi gbogbo nínú gbogbo ìjọ.