Kólósè 1:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ní báyìí, mò ń yọ̀ nínú ìyà tí mò ń jẹ lórí yín,+ mo sì ń ní ìpọ́njú Kristi tí mi ò tíì ní nínú ẹran ara mi nítorí ara rẹ̀,+ ìyẹn ìjọ.+ 2 Tímótì 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kí ìwọ náà múra tán láti jìyà+ nítorí ọmọ ogun rere+ fún Kristi Jésù ni ọ́.
24 Ní báyìí, mò ń yọ̀ nínú ìyà tí mò ń jẹ lórí yín,+ mo sì ń ní ìpọ́njú Kristi tí mi ò tíì ní nínú ẹran ara mi nítorí ara rẹ̀,+ ìyẹn ìjọ.+