Fílípì 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mo ní okun láti ṣe ohun gbogbo nípasẹ̀ ẹni tó ń fún mi lágbára.+ Kólósè 1:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 kí agbára rẹ̀ ológo sì fún yín ní gbogbo agbára tí ẹ nílò,+ kí ẹ lè fara dà á ní kíkún pẹ̀lú sùúrù àti ìdùnnú,
11 kí agbára rẹ̀ ológo sì fún yín ní gbogbo agbára tí ẹ nílò,+ kí ẹ lè fara dà á ní kíkún pẹ̀lú sùúrù àti ìdùnnú,