-
Róòmù 14:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Mo mọ̀, ó sì dá mi lójú nínú Jésù Olúwa pé kò sí nǹkan kan tí ó jẹ́ aláìmọ́ fúnra rẹ̀;+ àmọ́ tí ẹnì kan bá ka ohun kan sí aláìmọ́, ó máa jẹ́ aláìmọ́ lójú rẹ̀.
-