Éfésù 4:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Kí ẹni tó ń jalè má jalè mọ́; kàkà bẹ́ẹ̀, kó máa ṣiṣẹ́ kára, kó máa fi ọwọ́ rẹ̀ ṣe iṣẹ́ rere,+ kó lè ní nǹkan tó máa fún ẹni tí kò ní.+
28 Kí ẹni tó ń jalè má jalè mọ́; kàkà bẹ́ẹ̀, kó máa ṣiṣẹ́ kára, kó máa fi ọwọ́ rẹ̀ ṣe iṣẹ́ rere,+ kó lè ní nǹkan tó máa fún ẹni tí kò ní.+