Mátíù 5:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Bákan náà, ẹ jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ yín máa tàn níwájú àwọn èèyàn,+ kí wọ́n lè rí àwọn iṣẹ́ rere yín,+ kí wọ́n sì fògo fún Baba yín tó wà ní ọ̀run.+
16 Bákan náà, ẹ jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ yín máa tàn níwájú àwọn èèyàn,+ kí wọ́n lè rí àwọn iṣẹ́ rere yín,+ kí wọ́n sì fògo fún Baba yín tó wà ní ọ̀run.+