2 Pétérù 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 ní pàtàkì àwọn tó ń wá bí wọ́n ṣe máa sọ ẹran ara àwọn míì di aláìmọ́,+ tí wọn ò sì ka àwọn aláṣẹ sí.*+ Wọ́n gbójúgbóyà, wọ́n jẹ́ aṣetinú-ẹni, wọn ò sì bẹ̀rù láti sọ̀rọ̀ àwọn ẹni ògo láìdáa,
10 ní pàtàkì àwọn tó ń wá bí wọ́n ṣe máa sọ ẹran ara àwọn míì di aláìmọ́,+ tí wọn ò sì ka àwọn aláṣẹ sí.*+ Wọ́n gbójúgbóyà, wọ́n jẹ́ aṣetinú-ẹni, wọn ò sì bẹ̀rù láti sọ̀rọ̀ àwọn ẹni ògo láìdáa,