-
Éfésù 1:15, 16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ìdí nìyẹn tó fi jẹ́ pé látìgbà tí èmi náà ti gbọ́ nípa ìgbàgbọ́ tí ẹ ní nínú Jésù Olúwa àti nípa ìfẹ́ tí ẹ fi hàn sí gbogbo àwọn ẹni mímọ́, 16 mi ò yéé dúpẹ́ nítorí yín. Mo sì ń dárúkọ yín nínú àdúrà mi,
-
-
1 Tẹsalóníkà 1:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ìgbà gbogbo là ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run tí a bá ń rántí gbogbo yín nínú àdúrà wa,+
-