2 Sámúẹ́lì 7:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Màá di bàbá rẹ̀, á sì di ọmọ mi.+ Tí ó bá ṣe àìtọ́, màá fi ọ̀pá àti ẹgba àwọn ọmọ aráyé*+ bá a wí. Máàkù 1:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ohùn kan sì dún láti ọ̀run pé: “Ìwọ ni Ọmọ mi, àyànfẹ́; mo ti tẹ́wọ́ gbà ọ́.”+ Lúùkù 9:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ohùn kan+ wá dún látinú ìkùukùu náà pé: “Èyí ni Ọmọ mi, ẹni tí mo ti yàn.+ Ẹ fetí sí i.”+ 2 Pétérù 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí ó gba ọlá àti ògo láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run tó jẹ́ Baba, nígbà tí ògo ọlá ńlá sọ irú ọ̀rọ̀ yìí fún un* pé: “Èyí ni Ọmọ mi, àyànfẹ́ mi, ẹni tí èmi fúnra mi tẹ́wọ́ gbà.”+
14 Màá di bàbá rẹ̀, á sì di ọmọ mi.+ Tí ó bá ṣe àìtọ́, màá fi ọ̀pá àti ẹgba àwọn ọmọ aráyé*+ bá a wí.
17 Torí ó gba ọlá àti ògo láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run tó jẹ́ Baba, nígbà tí ògo ọlá ńlá sọ irú ọ̀rọ̀ yìí fún un* pé: “Èyí ni Ọmọ mi, àyànfẹ́ mi, ẹni tí èmi fúnra mi tẹ́wọ́ gbà.”+