Éfésù 4:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí náà, kò yẹ ká jẹ́ ọmọdé mọ́, tí à ń gbá kiri bí ìgbì òkun ṣe ń gbá nǹkan kiri, tí gbogbo ẹ̀fúùfù ẹ̀kọ́ ẹ̀tàn àwọn èèyàn sì ń gbá síbí sọ́hùn-ún+ nípasẹ̀ ọgbọ́nkọ́gbọ́n tí a fi hùmọ̀ ẹ̀tàn.
14 Torí náà, kò yẹ ká jẹ́ ọmọdé mọ́, tí à ń gbá kiri bí ìgbì òkun ṣe ń gbá nǹkan kiri, tí gbogbo ẹ̀fúùfù ẹ̀kọ́ ẹ̀tàn àwọn èèyàn sì ń gbá síbí sọ́hùn-ún+ nípasẹ̀ ọgbọ́nkọ́gbọ́n tí a fi hùmọ̀ ẹ̀tàn.