Jẹ́nẹ́sísì 31:53 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 53 Kí Ọlọ́run Ábúráhámù+ àti Ọlọ́run Náhórì, Ọlọ́run bàbá wọn ṣèdájọ́ láàárín wa.” Jékọ́bù sì fi Ẹni tí Ísákì bàbá rẹ̀ ń bẹ̀rù búra.*+
53 Kí Ọlọ́run Ábúráhámù+ àti Ọlọ́run Náhórì, Ọlọ́run bàbá wọn ṣèdájọ́ láàárín wa.” Jékọ́bù sì fi Ẹni tí Ísákì bàbá rẹ̀ ń bẹ̀rù búra.*+