Jẹ́nẹ́sísì 14:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ìyìn yẹ Ọlọ́run Gíga Jù Lọ, Ẹni tó mú kí ọwọ́ rẹ tẹ àwọn tó ń ni ọ́ lára!” Ábúrámù sì fún un ní ìdá mẹ́wàá gbogbo nǹkan.+
20 Ìyìn yẹ Ọlọ́run Gíga Jù Lọ, Ẹni tó mú kí ọwọ́ rẹ tẹ àwọn tó ń ni ọ́ lára!” Ábúrámù sì fún un ní ìdá mẹ́wàá gbogbo nǹkan.+