Hébérù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí náà, ẹ̀yin ará tí ẹ jẹ́ mímọ́, ẹ̀yin tí ẹ ní ìpè* ti ọ̀run,+ ẹ ronú nípa àpọ́sítélì àti àlùfáà àgbà tí a gbà,* ìyẹn Jésù.+ Hébérù 7:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Torí irú àlùfáà àgbà yìí ló yẹ wá, ẹni tó jẹ́ adúróṣinṣin, aláìṣẹ̀, aláìlẹ́gbin,+ ẹni tí a yà sọ́tọ̀ láàárín àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, tí a sì gbé ga ju ọ̀run lọ.+
3 Torí náà, ẹ̀yin ará tí ẹ jẹ́ mímọ́, ẹ̀yin tí ẹ ní ìpè* ti ọ̀run,+ ẹ ronú nípa àpọ́sítélì àti àlùfáà àgbà tí a gbà,* ìyẹn Jésù.+
26 Torí irú àlùfáà àgbà yìí ló yẹ wá, ẹni tó jẹ́ adúróṣinṣin, aláìṣẹ̀, aláìlẹ́gbin,+ ẹni tí a yà sọ́tọ̀ láàárín àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, tí a sì gbé ga ju ọ̀run lọ.+