Róòmù 6:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí a mọ̀ pé ní báyìí tí a ti gbé Kristi dìde kúrò nínú ikú,+ kò ní kú mọ́;+ ikú kò lágbára lórí rẹ̀ mọ́. 1 Tímótì 6:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 ẹnì kan ṣoṣo tó ní àìkú,+ ẹni tó ń gbé inú ìmọ́lẹ̀ tí kò ṣeé sún mọ́,+ tí èèyàn kankan kò rí rí, tí wọn ò sì lè rí.+ Òun ni kí ọlá àti agbára ayérayé jẹ́ tirẹ̀. Àmín.
9 Torí a mọ̀ pé ní báyìí tí a ti gbé Kristi dìde kúrò nínú ikú,+ kò ní kú mọ́;+ ikú kò lágbára lórí rẹ̀ mọ́.
16 ẹnì kan ṣoṣo tó ní àìkú,+ ẹni tó ń gbé inú ìmọ́lẹ̀ tí kò ṣeé sún mọ́,+ tí èèyàn kankan kò rí rí, tí wọn ò sì lè rí.+ Òun ni kí ọlá àti agbára ayérayé jẹ́ tirẹ̀. Àmín.