-
Léfítíkù 9:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Áárónì sún mọ́ pẹpẹ, ó sì pa ọmọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ tó jẹ́ tirẹ̀.+
-
-
Léfítíkù 9:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Lẹ́yìn náà, ó mú ọrẹ àwọn èèyàn náà wá, ó mú ewúrẹ́ tó fẹ́ fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ fún àwọn èèyàn náà, ó sì pa á, ó sì fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ bíi ti àkọ́kọ́.
-