Léfítíkù 16:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Kí Áárónì mú akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ wá, èyí tó jẹ́ tirẹ̀, kó sì ṣe ètùtù torí ara rẹ̀ àti ilé rẹ̀; lẹ́yìn náà, kó pa akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, tó jẹ́ tirẹ̀.+
11 “Kí Áárónì mú akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ wá, èyí tó jẹ́ tirẹ̀, kó sì ṣe ètùtù torí ara rẹ̀ àti ilé rẹ̀; lẹ́yìn náà, kó pa akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, tó jẹ́ tirẹ̀.+