-
Gálátíà 3:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Ṣé Òfin wá ta ko àwọn ìlérí Ọlọ́run ni? Kò rí bẹ́ẹ̀ rárá! Torí ká ní òfin tí a fún wa lè fúnni ní ìyè ni, òdodo ì bá ti wá nípasẹ̀ òfin.
-