Lúùkù 8:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ní ti èyí tó wà lórí iyẹ̀pẹ̀ tó dáa, àwọn yìí ló jẹ́ pé, lẹ́yìn tí wọ́n fi ọkàn tó tọ́, tó sì dáa gbọ́ ọ̀rọ̀ náà,+ wọ́n fi sọ́kàn, wọ́n sì ń fi ìfaradà so èso.+
15 Ní ti èyí tó wà lórí iyẹ̀pẹ̀ tó dáa, àwọn yìí ló jẹ́ pé, lẹ́yìn tí wọ́n fi ọkàn tó tọ́, tó sì dáa gbọ́ ọ̀rọ̀ náà,+ wọ́n fi sọ́kàn, wọ́n sì ń fi ìfaradà so èso.+