-
Nọ́ńbà 19:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Kí wọ́n bá aláìmọ́ náà bù lára eérú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n sun, kí wọ́n fi sínú ohun èlò kan, kí wọ́n sì bu omi tó ń ṣàn sí i.
-
-
Nọ́ńbà 19:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Kí ẹni tó mọ́ náà wọ́n ọn sára aláìmọ́ náà ní ọjọ́ kẹta àti ní ọjọ́ keje,+ kó sì wẹ̀ ẹ́ mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ ní ọjọ́ keje; kó wá fọ aṣọ rẹ̀, kó sì fi omi wẹ̀, yóò sì di mímọ́ ní alẹ́.
-