Mátíù 27:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 Wò ó! aṣọ ìdábùú ibi mímọ́+ ya sí méjì,+ látòkè dé ìsàlẹ̀,+ ilẹ̀ mì tìtì, àwọn àpáta sì là.