-
Hébérù 10:28, 29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 A kì í ṣàánú ẹnikẹ́ni tí kò bá ka Òfin Mósè sí, ó máa kú tí ẹni méjì tàbí mẹ́ta bá ti jẹ́rìí sí i.+ 29 Báwo lẹ ṣe wá rò pé ó yẹ kí ìyà tó máa jẹ ẹni tó tẹ Ọmọ Ọlọ́run mọ́lẹ̀ pọ̀ tó, tó ti ka ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú+ tí a fi sọ ọ́ di mímọ́ sí nǹkan yẹpẹrẹ, tó sì fi ìwà àfojúdi mú ẹ̀mí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí bínú?+
-