Àìsáyà 35:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ fún àwọn ọwọ́ tí kò lágbára lókun,Ẹ sì mú kí àwọn orúnkún tó ń gbọ̀n dúró gbọn-in.+ Róòmù 1:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nítorí àárò yín ń sọ mí, kí n lè fún yín ní ẹ̀bùn ẹ̀mí, kí ẹ lè fìdí múlẹ̀; 12 àbí, ká kúkú sọ pé, ká jọ fún ara wa ní ìṣírí+ nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan wa, tiyín àti tèmi.
11 Nítorí àárò yín ń sọ mí, kí n lè fún yín ní ẹ̀bùn ẹ̀mí, kí ẹ lè fìdí múlẹ̀; 12 àbí, ká kúkú sọ pé, ká jọ fún ara wa ní ìṣírí+ nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan wa, tiyín àti tèmi.