Lúùkù 16:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Bákan náà, mò ń sọ fún yín pé: Ẹ fi ọrọ̀ àìṣòdodo wá ọ̀rẹ́ fún ara yín,+ kó lè jẹ́ pé, tó bá kùnà, wọ́n máa lè gbà yín sínú àwọn ibùgbé ayérayé.+
9 “Bákan náà, mò ń sọ fún yín pé: Ẹ fi ọrọ̀ àìṣòdodo wá ọ̀rẹ́ fún ara yín,+ kó lè jẹ́ pé, tó bá kùnà, wọ́n máa lè gbà yín sínú àwọn ibùgbé ayérayé.+