Hébérù 11:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Gbogbo àwọn yìí ní ìgbàgbọ́ títí wọ́n fi kú, bí wọn ò tiẹ̀ rí àwọn ohun tí ó ṣèlérí náà gbà; + àmọ́ wọ́n rí i láti òkèèrè,+ wọ́n tẹ́wọ́ gbà á, wọ́n sì kéde ní gbangba pé àwọn jẹ́ àjèjì àti olùgbé fún ìgbà díẹ̀* ní ilẹ̀ náà.
13 Gbogbo àwọn yìí ní ìgbàgbọ́ títí wọ́n fi kú, bí wọn ò tiẹ̀ rí àwọn ohun tí ó ṣèlérí náà gbà; + àmọ́ wọ́n rí i láti òkèèrè,+ wọ́n tẹ́wọ́ gbà á, wọ́n sì kéde ní gbangba pé àwọn jẹ́ àjèjì àti olùgbé fún ìgbà díẹ̀* ní ilẹ̀ náà.