Jẹ́nẹ́sísì 5:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Lẹ́yìn tó bí Mètúsélà, Énọ́kù ń bá Ọlọ́run tòótọ́* rìn fún ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300) ọdún. Ó sì bí àwọn ọmọ lọ́kùnrin àti lóbìnrin. Júùdù 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Kódà, Énọ́kù+ tó jẹ́ ẹnì keje nínú ìran Ádámù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa wọn pé: “Wò ó! Jèhófà* dé pẹ̀lú ọ̀kẹ́ àìmọye* àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀,+
22 Lẹ́yìn tó bí Mètúsélà, Énọ́kù ń bá Ọlọ́run tòótọ́* rìn fún ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300) ọdún. Ó sì bí àwọn ọmọ lọ́kùnrin àti lóbìnrin.
14 Kódà, Énọ́kù+ tó jẹ́ ẹnì keje nínú ìran Ádámù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa wọn pé: “Wò ó! Jèhófà* dé pẹ̀lú ọ̀kẹ́ àìmọye* àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀,+