Jẹ́nẹ́sísì 6:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ Nóà rí ojúure Jèhófà. 9 Ìtàn Nóà nìyí. Olódodo ni Nóà.+ Ó fi hàn pé òun jẹ́ aláìlẹ́bi* láàárín àwọn tí wọ́n jọ gbé láyé.* Nóà bá Ọlọ́run tòótọ́+ rìn.
8 Àmọ́ Nóà rí ojúure Jèhófà. 9 Ìtàn Nóà nìyí. Olódodo ni Nóà.+ Ó fi hàn pé òun jẹ́ aláìlẹ́bi* láàárín àwọn tí wọ́n jọ gbé láyé.* Nóà bá Ọlọ́run tòótọ́+ rìn.