Jẹ́nẹ́sísì 6:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ìwọ fi igi olóje*+ ṣe áàkì* fún ara rẹ. Kí o ṣe àwọn yàrá sínú áàkì náà, kí o sì fi ọ̀dà bítúmẹ́nì+ bo inú àti ìta rẹ̀.
14 Ìwọ fi igi olóje*+ ṣe áàkì* fún ara rẹ. Kí o ṣe àwọn yàrá sínú áàkì náà, kí o sì fi ọ̀dà bítúmẹ́nì+ bo inú àti ìta rẹ̀.