Jẹ́nẹ́sísì 6:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nóà sì ṣe gbogbo ohun tí Ọlọ́run pa láṣẹ fún un. Ó ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́.+ 2 Pétérù 2:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kò sì fawọ́ sẹ́yìn láti fìyà jẹ ayé ìgbàanì,+ àmọ́ ó dá ẹ̀mí Nóà, oníwàásù òdodo sí+ pẹ̀lú àwọn méje míì + nígbà tó mú ìkún omi wá sórí ayé àwọn tí kò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run.+
5 Kò sì fawọ́ sẹ́yìn láti fìyà jẹ ayé ìgbàanì,+ àmọ́ ó dá ẹ̀mí Nóà, oníwàásù òdodo sí+ pẹ̀lú àwọn méje míì + nígbà tó mú ìkún omi wá sórí ayé àwọn tí kò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run.+