Jẹ́nẹ́sísì 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jèhófà sì sọ fún Ábúrámù pé: “Kúrò ní ilẹ̀ rẹ, kí o kúrò lọ́dọ̀ àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ àti ilé bàbá rẹ, kí o lọ sí ilẹ̀ tí màá fi hàn ọ́.+ Jẹ́nẹ́sísì 12:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Torí náà, Ábúrámù gbéra, bí Jèhófà ṣe sọ fún un, Lọ́ọ̀tì sì bá a lọ. Ẹni ọdún márùndínlọ́gọ́rin (75) ni Ábúrámù nígbà tó kúrò ní Háránì.+
12 Jèhófà sì sọ fún Ábúrámù pé: “Kúrò ní ilẹ̀ rẹ, kí o kúrò lọ́dọ̀ àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ àti ilé bàbá rẹ, kí o lọ sí ilẹ̀ tí màá fi hàn ọ́.+
4 Torí náà, Ábúrámù gbéra, bí Jèhófà ṣe sọ fún un, Lọ́ọ̀tì sì bá a lọ. Ẹni ọdún márùndínlọ́gọ́rin (75) ni Ábúrámù nígbà tó kúrò ní Háránì.+