Hébérù 11:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àmọ́ ní báyìí, wọ́n ń sapá láti dé ibi tó dáa jù, ìyẹn èyí tó jẹ́ ti ọ̀run. Torí náà, Ọlọ́run ò tijú, pé kí wọ́n máa pe òun ní Ọlọ́run wọn,+ torí ó ti ṣètò ìlú kan sílẹ̀ fún wọn.+
16 Àmọ́ ní báyìí, wọ́n ń sapá láti dé ibi tó dáa jù, ìyẹn èyí tó jẹ́ ti ọ̀run. Torí náà, Ọlọ́run ò tijú, pé kí wọ́n máa pe òun ní Ọlọ́run wọn,+ torí ó ti ṣètò ìlú kan sílẹ̀ fún wọn.+