Jẹ́nẹ́sísì 22:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 ó dájú pé màá bù kún ọ, ó sì dájú pé màá mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ bí àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run àti iyanrìn etí òkun,+ ọmọ* rẹ yóò sì gba ẹnubodè* àwọn ọ̀tá+ rẹ̀ lọ́wọ́ wọn. 1 Àwọn Ọba 4:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Júdà àti Ísírẹ́lì pọ̀ bí iyanrìn etí òkun;+ wọ́n ń jẹ, wọ́n ń mu, wọ́n sì ń yọ̀.+
17 ó dájú pé màá bù kún ọ, ó sì dájú pé màá mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ bí àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run àti iyanrìn etí òkun,+ ọmọ* rẹ yóò sì gba ẹnubodè* àwọn ọ̀tá+ rẹ̀ lọ́wọ́ wọn.