Ìṣe 7:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Lákòókò yẹn, wọ́n bí Mósè, Ọlọ́run sì fún un lẹ́wà gan-an.* Wọ́n fi oṣù mẹ́ta tọ́jú rẹ̀* ní ilé bàbá rẹ̀.+
20 Lákòókò yẹn, wọ́n bí Mósè, Ọlọ́run sì fún un lẹ́wà gan-an.* Wọ́n fi oṣù mẹ́ta tọ́jú rẹ̀* ní ilé bàbá rẹ̀.+