Ẹ́kísódù 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nígbà yẹn, lẹ́yìn tí Mósè dàgbà,* ó jáde lọ sọ́dọ̀ àwọn arákùnrin rẹ̀, kó lè lọ wo ìnira tí wọ́n ń fara dà,+ ó sì tajú kán rí ọmọ Íjíbítì kan tó ń lu Hébérù kan tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èèyàn rẹ̀.
11 Nígbà yẹn, lẹ́yìn tí Mósè dàgbà,* ó jáde lọ sọ́dọ̀ àwọn arákùnrin rẹ̀, kó lè lọ wo ìnira tí wọ́n ń fara dà,+ ó sì tajú kán rí ọmọ Íjíbítì kan tó ń lu Hébérù kan tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èèyàn rẹ̀.