-
Jóṣúà 6:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ní ọjọ́ keje, wọ́n dìde ní àárọ̀ kùtù, gbàrà tí ilẹ̀ mọ́, wọ́n sì yan yí ìlú náà ká lọ́nà kan náà lẹ́ẹ̀méje. Ọjọ́ yẹn nìkan ni wọ́n yan yí ìlú náà ká lẹ́ẹ̀méje.+
-