Àìsáyà 35:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ fún àwọn ọwọ́ tí kò lágbára lókun,Ẹ sì mú kí àwọn orúnkún tó ń gbọ̀n dúró gbọn-in.+